
Emi Lo Kan Lyrics by QDot Emilokan Lyrics
Read Official Lyrics Of Qdot's new song titled “Emilokan by QDot Emilokan Lyrics Of Emi Lo Kan by QDot Songs Lyrics.” A beautiful song that worth a listening pleasure, kindly be the next to read Emi Lokan Lyrics and sing along!
INTRO:
Omo mo moriamo
Qdot lorukomi
2tupondeebeatz
Kuronbeyen na
CHORUS:
Oshe ikinni lule
Oshekeji lule
Oshe keta lule
Edakun ema je ko se ikerin (emilokan)
VERSE 1:
Egbe kiniyi wa (emilokan)
kiniyi kini mi ni(emilokan)
Angeli ton pinre (emilokan)
Pinre kanmi (emilokan)
Mogbodo lowo(emilokan )
Omolorun ogbodo shesho (emilokan)
Ire owo (emilokan )
Ire omo (emilokan)
Alubarika (emilokan)
London wo inu America (emilokan)
Dubai wo canada (emilokan)
Bai lase ko oro mhi (emilokan)
Iran meta ogbodo to loshi(emilokan)
Korimi dori owo(emilokan)
Korimi dori apesin(emilokan)
God I need this blessing (emilokan)
CHORUS:
Oshe ikinni lule
Oshekeji lule
Oshe keta lule
Edakun ema je ko se ikerin (emilokan)
VERSE 2:
Odun yi, odun mi ni (emilokan)
Ori mi, ma jami ku'le (emilokan)
Olohun, ona wa mimo (emilokan)
Olohun asakiatu (emilokan)
Maleika waloda (emilokan)
K'aye ma bimi pe “Olohun mi da?” (emilokan)
Awon elenu shoh-shoh, shoh (emilokan)
Awon elenu sho-sho, sho (emilokan)
Won a de ma so'sokuso (emilokan)
Wo ola Bibeli re (emilokan)
Wo ola Qurani re (emilokan)
Wo ola kini awon baba mi kan (emilokan)
T'oun dun woro woro (emilokan)
Baba, maje n pofo (emilokan)
Baba, shey iyanu l'aye mi (emilokan)
Kinye f'ori olori toro (emilokan)
CHORUS:
Oshe ikinni lule
Oshekeji lule
Oshe keta lule
Edakun ema je ko se ikerin (emilokan)
VERSE 3:
Igbami l'ode (emi lo kan)
Omo Moriamo fe gb'ade (emi lo kan)
E soh fun Sunny al'Ade (emi lo kan)
Oro t'eba soh fun sango oh (emi lo kan)
Sango ma soh f'oya (emi lo kan)
E soh fun Dangote (emi lo kan)
Pe “ko soh fun Okoya” (emi lo kan)
Emi na fe ma sha'nu eniyan (emi lo kan)
Bi ti Dende n'Ilaro (emi lo kan)
MC f'owo yemi si (emi lo kan)
Mo mo Riliwan Kula (emi lo kan)
Eyan Paso (emilokan)
Alagbe ton fun alagbe l'owo (emi lo kan)
Arowolo lon ta motor (emi lo kan)
Dr. Brown (emi lo kan)
Lanre Typical (emi lo kan)
Tinba ni “hmm-mm, hmm-mm” (emi lo kan)
Tinba ni “eh-ehn, eh-ehn” (emi lo kan)
Wo, emi l'oye (emi lo kan)
Mio fe fi gbogbo enu s'oro (emi lo kan)
K'oma lo ti mi mo koro (emi lo kan)
Ao mo'yan l'Abuja (emi lo kan)
2T ma lu'lu, o ma dun (emi lo kan)
T'oba ti dun, o de ma dun (emi lo kan)
CHORUS:
Oshe ikinni lule
Oshekeji lule
Oshe keta lule
Edakun ema je ko se ikerin (emilokan)
Discussion about this post